No. 492Iran orun iwo ti leruLyrics1Iran orun iwo ti leru Iwo ti lewa to ninu okan mi Bi eru Re ti to bi to ni Beni ewa Re wu mi.2Wo Apoti majemu tawon ogun orun duro ti Lori oke Eri titi de petele, Pupo keke ogun nsare loke Eri Kikun won bo ile Eri.3Wo Odomokunrin ti oga ogo fi ororo yan Ju gbogbo awon elegbe re lo On to duro lori apoti eri Tawon Ogun nye si.4Gbogbo ogun Orun ati awon eda orun Si nfori bale fun odomokunrin na O ye fun awon omo Eri Lati, teriba fun Kristi.5Zion Eri ilu elewa pipe yi Ti ohun iselogo re ti ite Olorun wa Anu se mi fun awon omo Eri To npariwo nibe.6Ida nfo lati da orun wa Ohun kan nso lehin ida na pe Sioni je ilu onigbagbo Ibi isimi lparoro.7Sioni ilu ayo yi lariwo ti njade Sioni ilu ayo yi lariwo Ojo gba kan Anu se mi fun awon alatakun To npa okiti ariwo kiri.8Eje ka ma rin irin eto Salemu Eje ka ma to iwa pele Sioni yi Ki Ogun Olorun to sokale Ma ba fi ida pa wa.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Previous491 · Mo fi Ope fun o OluwaNext 493 · Nigbati iku baso midi erupe tan