No. 494O ye ka fi Ogbon aiye sileLyrics1O ye ka fi Ogbon aiye sile Nitori Oro Kristi Ako le tipa Ogbon aiye mo Olorun Gbogbo ero Ogbon aiye yi Je were lodo Olorun Ogbon aiye kole mu ni mo Olorun.2Ko si ere ninu Ogbon aiye Bi kose Ole jija Ati pansaga pelu igberaga Ija ati agidi pelu ojukokoro Nwon lere'to wa ninu Ogbon aiye.3Awon to nhuwa ole Ati awon aborisa Kole ni ipin ninu ile Olorun Eniti Kristi ba nto Tl ko ba huwa wonyi On ni yio ba Olorun joba.4Oluwa mu wa teriba Bi ategun ti nte Igi ba Gba ogbon aiye kuro ninu okan wa Fi agbara ogbon tire nikan Kun gbogbo wa lokan Ki ogbon aiye le di ofo loju wa.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Previous493 · Nigbati iku baso midi erupe tanNext 495 · Oro ogbon ati oro edidi