No. 493Nigbati iku baso midi erupe tanLyrics1Nigbati iku baso midi erupe tan Bawo ni ewa ojiji ara mi yio tiri Koha ni yipada ko ha ni yipada Ewa ara mi yio parun gbati iku ba pa mi.2Nigbati orun ti nba ara je ba de si mi Bawo ni imu mi ato oju mi yio ti ri Ko ha ni yipada? ko ha ni yipada? Ko ha ni sun omi eje, tawon eda yo tuto si.3Bawoni iyepe arami yio ti po to Ko di onje fun awon idin lati je Baba mase jeki npe ninu erupe Ki o to se idajo aye ati awon Oku.4Wo bi iku ti nso ewa elewa di egbin Tosi ntu asiri gbogbo awon gbajumo Ibiti a nfi aso bo - ni iku so di ihoho Bawo lemi yio ti ri lojo iku temi?5Nigbati iku ba so ara mi di Oku tan Emi hale pe ninu ile ki Idajo to de A! Oluwa mi bo sepe emi yio pe Fi agbara emi re gbe mi gun oke Alore.6Baba mase jeki isa-oku gbe mi mi laiye Mase jeki idin le fi ara mi se onje je Fi Emi ajinde re gbe mi wole Isin mi re Ki emi le ba awon egbe Orun yin O.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Previous492 · Iran orun iwo ti leruNext 494 · O ye ka fi Ogbon aiye sile