No. 496Ijosin aiye le dunLyrics1Ijosin aiye le dun Ko le dun bi torun Enyin sa ni iyo aiye Ti mu aiye dun2Gbati awon ayanfe Ba ti aiye kuro Gbogbo ogo aiye yi, Yio sun Okunkun.3Tori loti ni kan Ikilo ba Sodomu Gbati won ko ikilo na Nwon si segbe.4Onje aiye le dun Kole dun bi t' orun Ko si bi a ti je onje aiye to Ki awa ma ke ebi5Ogo Kristi sokale Tori awon oloto Bi a ba tele ogo na A o di alare.6Ikede ati Ikilo Wa fun awon arufin Bi won ba ko ikilo na. Nwon yio gba idajo.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Previous495 · Oro ogbon ati oro edidiNext 497 · Mo ngbo ohun Oluwa pe