No. 497Mo ngbo ohun Oluwa peLyrics1Mo ngbo ohun Oluwa pe Ina lere ibi Mo ngbo ohun Oluwa pe Ina lere ibi2Mo ngbo ohun Oluwa pe Ibi lere ibi Mo ngbo ohun Oluwa pe Rere lere ire3Mo ngbo ohun Oluwa pe Emi lonje iye Mo ngbo ohun Oluwa pe Ngbo fo ibode orun apaidi4Mo ngbo ohun Oluwa pe Awon ayanfe yio jogun aiye Mo ngbo ohun Oluwa pe Ki awa tele on5Mo ngbo ohun Oluwa pe Ewo tempili yi pale Emi yio gbe dide Ni iwoyi ojo keta.6Mo ngbo ohun Oluwa pe Emi lona igbala Eni ba wa sodo mi Yio wole ijoba Orun.7Mo ngbo ohun Oluwa pe Emi l'oluso Agutan Emi ni alakoso Fun gbogbo awon ayanfe8Mo ngbo ohun Oluwa pe Enyin oku ni e mi Mo ngbo ohun Oluwa pe E gun oke sinu ayo.9Oluwa nso leti mi Enyin oku mi e ji E bo sinu Imole Ati ewa ogo mi10Mo ngbo ohun Oluwa pe Bi e ba tele mi Nigbati enyin ba ku Emi yio ji nyin dide.11Mo ngbo ohun Oluwa pe Wa sodo mi alare Emi o tun O ninu ide re Ngo fun O ni itura okan12Mo ngbo ohun Oluwa pe E ni ba gba mi o gba Olorun Mo ngbo Ohun Oluwa pe Eni ko mi ko Olorun.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Previous496 · Ijosin aiye le dunNext 498 · E si ipo nyin pada