No. 499Wura ati fadaka emi ko niLyrics1Wura ati fadaka emi ko ni Lati fifun enyin ti e nsagbe Sugbon loruko Kristi ti Nasareti Alagbe ati alaisan e dide.2Oluwa jo fun mi l'emi Ijigiri Lati ji gbogbo awon alare Fun mi lagbara lori emi aimo Ki nfi emi re le emi esu jade.3Gba isekise kuro lowo mi Ki o si da aya titun sinu mi Jo fi Ogo re han lara mi Larin Ijo ati nibi gbogbo.4Owo ati aso emi ko ni Lati ta awon alaisan lore Sugbon loruko Kristi Oga Ogo E gbe akete nyin e dide.5Oluwa jo fi mi se Iwosan Fun gbogbo awon alaisan Oluwa jo fi mi se Onde Fun gbogbo awon ti esu de.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Iwosan fun Alaisan Orin Mimo Sainary Alore Previous498 · E si ipo nyin padaNext 500 · Emi o ma se Oluwa loba