No. 498E si ipo nyin padaLyrics1E si ipo nyin pada Enyin Igbekun to wa ni Zion E si ipo nyin pada Beni Oluwa wi.2E yara sokale Enyin eranko to gun Sion E yara sokale Beni emi nso.3E mu igberaga kuro Gbogbo enyin Omo eke E mase se efe mo Beni emi nwi.4E ronu ---Piwada Gbogbo eyin elese E se Ijewo ese nyin Beni emi nso.5Gbogbo enyin alaigbagbo E yi pada si-Oluwa Oluwa yio gba nyin Kuro lowo esu6Gbogbo enyin Onigbagbo E mase se are mo E pe Olorun loba nyin Yio si gba yin la.7A o tu Ihoho nyin Enyin Igbekun to gun Sioni A o tu ihoho nyin Beni Oluwa nwi.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Previous497 · Mo ngbo ohun Oluwa peNext 499 · Wura ati fadaka emi ko ni