No. 506Wo ekun mi o RakeliLyrics1Wo ekun mi o Rakeli mi o wo ekun mi Wo ekun mi o Rakeli2Gbogbo koriko to ro eji dide E so ara yin di omo oro3Wo ekun ti mo nsun nitori omo oro Wo ekun mi o Rakeli4Iwo ALore omo oro Sensiry Wo ekun omo ti mo nsun5Wo ekun mi o Rakeli mi o wo ekun mi Bi Olorun ti wo ekun re6Gbogbo e osun to nu e fi ara han E ji dide tan imole7Enyin Osupa to sokunkun etan imole ka le ri imole yin lo.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryItore Anu fun Awon Agan Orin Mimo Sainary Alore Previous505 · Gbogbo awon egbe Ogun OrunNext 507 · Lori Oke mo wa yi o