Before you read

No. 507

Lori Oke mo wa yi o

Lyrics

Chorus

Nwon nko mi bi emi o ti sin Oluwa Lori Oke mo wa yi o Mo ba egbe Alore pade

Chorus

Nwon nmi imisi isin si agbala ihin Lori oke mo wa yi o Mo ba Egbe awon alore pade.

Chorus

Gbogbo igberaga mi ni Olorun gba Lori oke ti mo wa yi o Mo ba egbe awon alore pade.

Chorus

Oluwa fun mi nipe lati ji awon to sun Lori oke ti Mo de yi Mo ba egbe awon Alore pade.

Chorus

Baba fi orin emi re kun okan mi Fi kun ereke mi lojojo Ko han ninu mi ati lode ara mi.

Amin

About this hymn

Written by
Prophet Mennary

Orin Mimo Sainary Alore