No. 510Ire ti Oluwa su logba EdenLyrics1Ire ti Oluwa su logba Eden O wa titi di oni yi Egun ti Olorun gun logba Eden O wa titi di oni yi2Iwo okuta Jasipi Iwo ti lewa pupo Kerubu to fe ba o ja Ni OLuwa mu kuro3Oluwa gba orin ogo Kuro lowo awon aiye O ngbe fun awon talaka Ati awon ewe omode4Ope ni fun Olorun ni SIoni To so eri kale fun wa To fun wa ni duru Orun Lati fi orin Re fo itegun aiye5Iwo ilu eri Zion Ilu ti Olorun fi emi se logo Nibe lawon ewe orun ti nbo Ti oruko emi si ntele won6Ilu alayo ni ilu Zion Nibe lemi ti nfi awon Woli sere Nibe lemi ti nfi awon Olorin sere Ti ewa orun sin bale won.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Previous509 · Ko orin Ogo - korin huriamuNext 511 · Yin, yin, yin-yin Olorun eleda re