No. 509Ko orin Ogo - korin huriamuLyrics1Ko orin Ogo - korin huriamu Si Olorun to nso o2So oro wala - So oro keu Si Olorun to nso o3Soro ododo - soro otito n enia Si Olorun eleda re4Wo apa to han ninu afefe O nbi pupo ile nla subu5Wo ojo to yo ni ite ofurufu Oju ojo na pon pupo6Oju Olorun nwo mi bi mo wa ninu ile ko si ohun to pamo loju re7Wo oju to yo- larin ite ofurufu Oju na nwo gbogbo aiye8Iran ti mo ri ni wakati kefa yi Emi ko ri ohun ere nibe9Kilohun to le gba o - ninu ogun ti mbo Oluwa nikan lo le gba o10Ko orin ogo-korin hariamu Si Olorun eleda re.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Previous508 · Nigba aro ati ayoNext 510 · Ire ti Oluwa su logba Eden