No. 531Nigbati mo ri manamana to lo lori oke ZionLyrics1Nigbati mo ri manamana to lo lori oke Zion 2ce Wo Manah,wo manah, wo manah Elio2Nigbati mo ri awon Alore To nkorin loke 2ce Wo Elio 3ce Sainah.3Wo bi ite Orun ti si 2ce Lori oke sama Awon Angeli sokale Miriri miriri mirriri o Mennah.4Wo awon Angeli to nfo 2ce Lori oke sama Won gbe wala Eri nbo O' Malo 3ce O Mennah.5Okan mi kun fun ayo 2ce Nipa iran na Ti mo ri ni pepe O malo 3ce o Mennah.6Awosanma be okan mi 2ce Nipa awon Angeli Ti mo ri loke mi Malo mi, malo mi, malo mi Alore.7Ide ese mi ja Gbati kristi pe mi 3ce Mo si je ipe na Ma ko mi 3ce O Alore.8Imole Orun ti tan Ninu okan mi . Gbati kristi nbe nibe 2ce O malo 3ce O Elio.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Ni Wednesday E. V. S 17 / 6/ 64 TFHCFABHW Previous530 · Misiry lau dauNext 532 · Ariwo bo temple