No. 532Ariwo bo templeLyrics1Ariwo bo temple Iyin si gba ori ite kan Nigbati Oluwa wole Hosannah Jesu nbo.2Wo awon eiye alekelede Ti nti oju ile de oju ile Won nyo ayo harpu Jesu Hosannah Jesu nbo.3Wo awon Adaba lori ite Ti nte ite ogo sile Won pese aiye sile fun Ona ihinrere Jesu4Wo bi awon Adaba Mennary Ti nra loke baba Won fi iye wo iye ara won Hosannah Jesu nbo.5Irawo ila Orun Kiniun eya Juda Ma bo lodo mi loni Hosannah Jesu nbo.6Odo agutan ti aiye ti pa Emi re la ngbe bo yi O nbo fun idande ayanfe Hosannah Jesu nbo.7Ariwo gba temple kan Nipa iro aiye Jesu Holy Holy kun gbogbo ile Iya si mimo Angeli ni8Holy Holy kun gbogbo ile Awon Adaba emi nbo Nipa odo Agutan ti nbo Aleluyah Jesu nbo9Ayo kun gbogbo ile Awon Akorin si nkorin Nipa odo Agutan ti nbo Aleluyah Jesu nbo.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Ni Sunday E.V.S. 21:6:64 TFHCFABHW Previous531 · Nigbati mo ri manamana to lo lori oke ZionNext 533 · So itan orun fun mi