No. 536Melo melo melo Ralo AloreLyrics1Melo melo melo Ralo Alore Melo melo melo ralo Aigbagbo lo pa sodomu run araiye Melo melo, melo melo.2Gbati mori Angeli Olorun araiye To duro sarin tempili Ko si eniti o le pa itan lori emi araiye Melo melo melo ralo3Eda le ma ri oro Olorun gbo araiye Lati odo awon Angeli mimo Ise Olorun awamaridi ni araiye O je edidi lori aiye.4Wo bi awon Angeli Olorun araiye Ti nlo iwa pele lorun Wo bi awon alore olorin araiye Ti nlo wa mimo lorun.5Wo bi willo orin ti nko Harpu araiye Ti harpu si nkorin Olufe Re Huspah wa ni idi frueted araiye T'awon Angeli nra loke won6Wo efin mimo ti mori araiye Ninu iran emi Atore Adaba Mennary nta okun orin araiye Ninu iran emi alore.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Previous535 · Mo nikan nrin nigberiko aiyeNext 537 · Nigba idajo Raibi Cake o