No. 537Nigba idajo Raibi Cake oLyrics1Nigba idajo Raibi Cake o Ki olori du ori re o Oro edidi lowa nibe o Ki alara so ara re o2Mana ko ni ila orun o O de iwo orun o Ohun ati aira jade lo Si gbogbo orile aye3Ni igba ihoho Raibi Sangar Ki alara sora re Ihoho Raibbi Sangar ki de Ki olododo ma subu4Romely Eli Elijah Temi dowo re Mase jeki nle subu Ni igba idajo aihabu o.5Baba wo Raibbi Sangar Ti nta iru idi re o Lati mu awon Nasiri Subu nipa eke re o6Mary ndau nile Salau o Kristi ologo de Oro orun ni ki ewo Enyin Nasiri Baba.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo ni Monday Tani le ka ami eranko buburu ni, Ami re je otalelegbeta ole mefa Mase sure lo kiakia lati ja. Nihin ni Suru awon enia mimo gbe wa T. H. R Previous536 · Melo melo melo Ralo AloreNext 538 · Hosannah Hosannah o Baba