No. 54 · Orin Iyin ati ỌpẹGbọ, gbọ, gbọ orin JubbiliLyrics1Gbọ, gbọ, gbọ orin Jubbili Orin iyin Ẹlẹda wa Gbọ bi iro rẹ ti ndun - jakejado Araiye ẹ wa, k’ayin Ọlọrun.2Wo b’awọn ẹgbẹ ọrun ti nda wọle Nwọn kọrin ti Jubbilie Gbọ bi iro rẹ ti ndun bi iro agogo Araiye ẹ wa ka sin Ọlọrun.3Yin, yin Ọlọrun ẹlẹda rẹ To fun Ọ lẹbun ini To fọmọ rẹ rubọ fun ọ Ki o le gba ọ, lọwọ ẹşe4Gbogbo ẹnyin idile ati iran Ẹ kọrin ti Jubbilei Ẹ sọrọ ọdun jubbilei fun gbogbo aiye Ka kọrin yin na.5Gbogbo awọn Onigbagbọ igbani To nkọrin ti jubbilie Nwọn nkọrin na pẹlu ọkan mimọ Nwọn ko kọ fun afẹ aiye.6Gbogbo ẹyin orile ede aiye To ngborin jubbilie Ẹ yi ara yin kan nidile idile Àraiye ẹ wa k’ ayin Ọlọrun.Amin.About this hymnWritten byProphet MennaryORIN MIMỌ SAINARY ALORESimilar hymns1Opo eri te ro - Awon omo Eri nsokun1957 · Orin Iyin ati Ọpẹ4Oba Oloro – foro sakoso lori Ijo TireOrin Adura5Gborin didun kan ti mo gboOrin Jesu Kristi6Geography ọrun ti Ọlọrun fi fun wa1959 · Orin Iwa Mimọ Previous53 · Romennah Romennah Sondau laui (2ce.)Next 55 · Ẹda to da mi bọ o