No. 55Oba rere oba alayo oba otitoLyrics1Oba rere Oba alayo Oba otito Yara sanu fun wa o Oba ire Igbi aye nba mi ja l'aye o Oro aye n dan ni wo nigba gbogbo Oba rere Oba alayo oba otito Yara se anu fun wa o oba ire2Ja Jehovah Oba alayo oba otito Yara se anu fun wa o Oba ire Ere wo lo wa ninu eje mi Gbati mo ba lo sinu iho Erupe ko le yin o Oba otito yara sanu fun wa o oba ire3Pupo omo eri tu kakiri lo si ile gbogbo Yara sanu fun wa o oba rere Majeki won rufin re ni igbekun Bi aye ba won ja ki won bori o Oba rere - Oba alayo Oba otito Yara sanu fun wa o Oba rere4Mahamadu Alau dalau Oba otito Yara sanu fun wa o Oba ire Kiniun aye nba wa ja lojo gbogbo Imo aiye nba wa ja lojo gbogbo Oba rere oba alayo oba otito Yara se anu fun wa o oba ireAbout this hymnWritten byProphet MennaryYear1957ORIN MIMO NI SATURDAY NIGHT 1/2/57Similar hymns1Opo eri te ro - Awon omo Eri nsokun1957 · Orin Iyin ati Ọpẹ4Oba Oloro – foro sakoso lori Ijo Tire1957 · Orin Ijo Zion7Afurugbin oro Olorun1964 · Orin Ikilọ8Wo pẹtẹlẹ ologo didan1957 · Orin Isipaya Previous54 · Fun mi lomo bi OluwaNext 56 · Olori ijo t'ọrun