No. 57 · Orin Isipaya · Orin AduraNinu awosanma to duroLyrics1Ninu awosanma to duro Lori oke ile Oluwa Baba ma jeki nsi iran ri Ninu ogbon Orun ti mbo yi Olorun fun mi lagbara Lati mo Oro edidi re.2Gbati mo wa ninu okunkun Jesu lo nse imole mi O nkigbe lohun jeje pe Omo mi kuro lokunkun Mo bo ago ara sile Mo si ngboro lodo Olorun.3Gbati esu ninu itanje re Gbe itanje re siwaju mi To ni ki nteriba fun on Ki emi si gba oro lodo on Olorun ran emi re si mi Kin le bo ninu idanwo esu.4Bi mo ti nrin lona ajo mi Imole kan si mo si mi Mo gbo ohun ninu imole na Wipe Omo gba edidi K’o si pin fun Orile- Ede Ti nwon kuna ninu Ogo mi5Olorun Olumo okan To mo ero inu Annaniah To gbete Woli soro fun Wipe O seke si Emi mimo Masai gba ete wa soro Lati da ete eke lebi.Amin.About this hymnWritten byProphet MennaryORIN MIMO SAINARY ALORESimilar hymns118Mo gbọro pe ẹmi ko si laiye1958 · Orin Isipaya58Ninu efa to kojaOrin Isipaya92Gbati mo wa ninu ẹmi OluwaOrin Isipaya197Emi-Mimo gbe mi gun okeOrin Isipaya Previous56 · Olori ijo t'ọrunNext 58 · Ninu efa to koja