No. 58 · Orin Isipaya · Orin AsoteleNinu efa to kojaLyrics1Ninu efa to koja Lojo ketalelogun Mo nlo si ile Olorun mi.2‘Gbati mo de ile adura Oluwa la mi loju Lati mo ogbon ati Oye.3‘Gbana mo ri okunrin kan L’aworan omo enia O si mu iwe kan dani4O nkigbe lohun jeje O sare wa sodo mi O si fun mi ni iwe na5Mo bere itumo iwe na O si nda mi lohun pe Mo fun o ni ihinrere6Iwariri si mu mi Nitori oro edidi yi Omije nsan loju mi7O wa ninu awo sanma O nwi lohun jeje pe ERI loro edidi8‘Gbati o fun mi ledidi O fun mi leri pelu O fun mi loro Olorun9Imole Kan si mo si mi 'Gbati o fun mi ledidi Mo gbagbe Ogo aiye.10Olorun alagbara 'Wo to fun mi ledidi Majeki nsi oro so.11Jesu omo Olorun Iwo to fun wa loro eri Jek’ ajeri na de opin.12‘Gbati mo ri oro re nlo Jeki nku ninu iku re Jeki nle ba o jinde. Amin.Amin.About this hymnWritten byProphet MennaryORIN MIMO C/S ORIN IMO NINU EMI OLUWA The Hermmar RomissionSimilar hymns57Ninu awosanma to duroOrin Isipaya118Mo gbọro pe ẹmi ko si laiye1958 · Orin Isipaya92Gbati mo wa ninu ẹmi OluwaOrin Isipaya59Oju awọn Nasiry, kole ku fun iran ririOrin Isipaya Previous57 · Ninu awosanma to duroNext 59 · Oju awọn Nasiry, kole ku fun iran riri