No. 88 · Orin Ajinde · Orin Awon to ntoro omoNinu ajinde ekiniLyrics1Ninu ajinde ekini Ti a ṣe ninu ẹri Oluwa jọ fi ara han wa Ki awa le gba Ọ gbọ.2Kristi Oluwa awa mbẹ Ọ Fara han nitotọ Iwọ to fi ara han Thomas Jọ fi ara han mi.3Ninu ajinde ti a wayi Fi agbara rẹ han mi Jẹki agan le di Ọlọmọ Ji ọmọ to ku dide.4O ṣe iṣẹ iyanu pupọ Lọdọ awọn Apostle Gbana ni wọn ni igboya Lati tọ Ọ lẹhin.5Ji gbogbo ọmọ ti eşu pa Fun awọn to nsọkun ọmọ Gbe ọmọ dide fun awọn Obirin Lakoko ajinde yi6Fi ẹkọ fun awọn to lẹmi rẹ Fi ọgbọn fun awọn to nlo Maşe jẹki awa iyoku Le şina lẹhin Rẹ.Amin.About this hymnWritten byProphet MennaryORIN MIMỌ SAINARY ALORESimilar hymns89Ọmọ Baba awa mbẹ ỌOrin Ajinde86Jesu awa ti duro toOrin Ajinde87Mo ri Ọrọ kan gbọ ninu BibeliOrin Ajinde83Awa ọmọ kekekeOrin Ajinde Previous87 · Mo ri Ọrọ kan gbọ ninu BibeliNext 89 · Ọmọ Baba awa mbẹ Ọ