No. 96 · Orin Ekun AloreOju mi si su okunkunLyrics1Oju mi si su okunkun Elo Raudalo Oju mi si su omije To Elo Raubbi mi.2Iṣogo Ẹri mi da ? Elo Raudalo Emi ko ni iṣogo Ẹri mọ Ẹri Elo Raubbi mi.3Agọ Ẹri lọ nwo lulẹ Awọn ọmọ Ẹri nṣubu Okunkun bo Sanma Ẹri Elo Raubbi mi.4Akoko itẹ ọrun l' eyi Elo Raudalo Ipe ikẹhin lo de yi Elo Raubbi mi.5Ogun ọrun takasọ sọna mi Elo Raudalo Adaba ntẹ waya lokẹ Elo Raubbi mi.6Duru mi ko igi willo Elo Raudalo Ahọn orin ko si mọ Elo Raubbi mi.7Ori Adaba mi wule Nigbati ori mi Oju mi si sun omije Elo Raubbi mi.Amin.About this hymnWritten byProphet MennaryORIN MIMỌ SAINARY ALORESimilar hymns109Mo fi duru mi kọ igi willoh (2ce.)1964 · Orin Ekun Alore120Adaba ẹri mi o, nibo lore o ?Orin Ekun Alore49Ni abọ pada irin ajo miOrin Ekun Alore162Mo nikan wa ninu Ogba1959 · Orin Ekun Alore Previous95 · Wo ẹkun mi o, Rakeli mi oNext 97 · Ero mi da rudu-rudu