No. 100 · Orin Woli, Iran ati Ẹmi Mimọ · Orin Ẹri ati IpeNinu awosanma to duroLyrics1Ninu awosanma to duro Lori oke ile Oluwa Baba ma jeki nsi iran ri Ninu ogbon Orun ti mbo yi Olorun fun mi lagbara Lati mo Oro edidi re.2Gbati mo wa ninu okunkun Jesu lo nse imole mi O nkigbe lohun jeje pe Omo mi kuro lokunkun Mo bo ago ara sile Mo si ngboro lodo Olorun.3Gbati esu ninu itanje re Gbe itanje re siwaju mi To ni ki nteriba fun on Ki emi si gba oro lodo on Olorun ran emi re si mi Kin le bo ninu idanwo esu.4Bi mo ti nrin lona ajo mi Imole kan si mo si mi Mo gbo ohun ninu imole na Wipe Omo gba edidi K’o si pin fun Orile- Ede Ti nwon kuna ninu Ogo mi5Olorun Olumo okan To mo ero inu Annaniah To gbete Woli soro fun Wipe O seke si Emi mimo Masai gba ete wa soro Lati da ete eke lebi.Amin.About this hymnWritten byProphet MennaryORIN MIMO SAINARY ALORESimilar hymns9Elo Hermar - Elo HermarOrin Woli, Iran ati Ẹmi Mimọ20Romicinah - Mary Alau-Dauher1956 · Orin Ọrun ati Iye Ainipẹkun21Mo ngbọ ọrọ edidi ọrun 1957 · Orin Woli, Iran ati Ẹmi Mimọ22Igba ogun ni ki Woli jaOrin Woli, Iran ati Ẹmi Mimọ Previous99 · Irawo didan omo DafidiNext 101 · Olugbala mo dupe