No. 217Gbati mo wa laiye'aiye feran miLyrics1Gbati mo wa laiye'aiye feran mi Mo fi ogo aiye sile' aiye kaga mi Gbogbo elegbe mi si fi mi nse sin Nwon sin bi mi lohun ti e mi ko mo2Gbogbo omo eke ati ohale E wa sodo Jesu, ki e gba omi iye Jeje lo nkigbe si awon omo re Wipe omo mi wa simi lodo mi3Gbogbo oye to wa ni igbagbo igbani Emi olukoni lo nfi won je oye Ifi ororo yan lo nko won leko Lati mo ogbon orun ati Ijinle re4Pupo oye to wa laiye isisiyi Ewo lo le ko ni loro Olorun? Tabi ki won riran otito fun ni? Ewo lo le soro ijinle fun wa?5Gbogbo oye to wa ti Olorun ko yan Nwon ko le fi oro han fun ni Nwon yo ma ko ni leko aye asan yı Nwon ko lagbara lati mo ogbon orun6Gbogbo ijoye aiye e gbo oro yi Bi enyin tile woso bi ti kegbe Laisi otito eniyan yio segbe. Omo kekere ti ri ogbon Olorun7Agba toye kun fun singan otito Ite ese ko le ba Olorun K'Angeli Nwon ro pe won ngbeja fun Olorun Nwon si nfurugbin ese nwon yo bi iparunAminAbout this hymnWritten byProphet MennaryTuneILE EWA WON NI Previous216 · Olorun mi ebe ni mo nbe ONext 218 · Olorun Metalokan awa omo re