No. 12 · Orin Isegun · Orin IdandeNi riru omi ẹba odo aiye yiLyrics1Ni riru omi ẹba odo aiye yi Lawọn aṣaju wa rekọja lọ Nwọn ṣegun awọn kiniun aiye o Eli o, Eli o, Eli o.2Omi yi gbogbo awọn olotọ ka Ti ki iṣe agbara omi Ọlọrun Eṣu wọ inu omi aiye nlu wa o Eli o, Eli o, Eli o.3Eṣu nda omi aiye lu Mary Nipa ọmọ ologo inu rẹ Ṣugbọn ilẹ ran Mary lọwọ o Eli o, Eli o, Eli o.4Wo bi igbin aiye ti nyi mi ka Nko lọgbọn ti ngo fi re kọja Fi iyẹ Adaba rẹ si apa mi o Ki nle fi re kọja.5Ọna ewo lemi o gba re kọja Ninu riru omi odo aiye yi Ọlọrun iwọ lo le ṣọ mi Gba mi o Baba ṣọ mi.Amin.About this hymnWritten byProphet MennaryORIN MIMỌSimilar hymns9Fi ara re fun Olorun1957 · Orin Isegun13Ajagun ma beruOrin Isegun201Bi isoro aiye yi ba nkan ilekunOrin Isegun23Olorun mi jo gba miOrin Idande Previous11 · Gbogbo ẹnyin Nasiry igbaniNext 13 · Ajagun ma beru