No. 73 · Orin Awon to ntoro omoKọrin iwọ agan ti ko biLyrics1Kọrin iwọ agan ti ko bi Bu sorin si ke rara Iwọ ti ko rọbiri yio di ọlọmọ.2Ọmọ awọn ti nsọkun ọmọ Yio pọ ni ijọba Siloh Agan sa tun ọkan rẹ ṣe Iwọ yio ri ọmọ bi.3Ẹnyin yio ya si apa ọtun Ẹ o ya si apa osi Iru ọmọ yi yio jogun Awọn keferi4Ma bẹru ọmọbinrin Nitori oju ki yio ti yin Iru ọmọ tiẹ o bi Yio jogun aiye.5Nigbati ẹnyin yio bimọ Ẹ o gbagbe itiju yin Ẹko ni ranti ẹgan yin Ati igba opo yin.6Ẹlẹda yin lọkọ yin Oluwa awọn ọmọ ogun Oluranpada ẹda ẹmi mimọ.Amin.About this hymnWritten byProphet MennaryORIN ITỌRỌ FUN AWỌN AGAN THE HAMMAR ROMISIONALLYSimilar hymns171Alaudauher, AlaudauherOrin Awon to ntoro omo157Kristi omo Baba, mo wa be oOrin Awon to ntoro omo176Asia Mininah duroOrin Awon to ntoro omo128Alore Mininah MinahOrin Awon to ntoro omo Previous72 · Ọmọ Alade alafiaNext 74 · Romicinah - Mary Alau-Dauher