No. 140 · Orin Ikilọ · Orin AjindeMase tori Mamoni alaistitoLyrics1Mase tori Mamoni alaistito o 2ce Ju amure re sonu Mase tori mamoni alaisotito Ba ipin emi je2Emi lo ko wa gun ori oke Zion Owo ko enia jade Mase tori mamoni alaisotito o. Ba ipin emi je3Ko sotito ninu oro mamoni Aworan kesari nise Mamoni mu baba seke somọ rẹ O mu omo nseke si baba4Mamori mu Gehasi gbe ete Namani O mu Judasi segbe o O mu Tokotaya segbe lojo kan Aworan kesari iku, ni5Eje Jesu iyebiye Fitura fokan mi Eni ba gbekele oro mamoni Yio di ọmọ kesari6Iranse kan kole sin baba meji Beni emi mimo nsọ A kole, sin Olorun pelu mamoni E gba oro yi ro ijo Amin.Amin.About this hymnWritten byProphet MennaryORIN MIMO EXM. SAINARY ALORE JESUSimilar hymns62Ẹmi gbe mi bi edidi si ayeOrin Ikilọ16Awọn kan ntẹle eşuOrin Ikilọ189Mo be Olorun mi1964 · Orin Ikilọ93Enia ti a bi ninu ObinrinOrin Ikilọ Previous139 · Keu Nasiry Mennah Alau dauNext 141 · MARIA MIMO -wo omo re o