No. 148 · Orin Ijo ZionEro ya wa wo ilu ogo (2ce)Lyrics1Ero ya wa wo ilu ogo (2ce) Imole Kristi tan wa loke sion, ero ya wa wo ilu ogo, ilu Elegbogi di asan ilu oni imolẹ di asan. ilu ti adura tedo dalagbara Ero ya wa wo ilu ogo2Wo Zion ilu Elewa ti a ti owo Elisah tẹdo nipa adura ero ya wa wo ilu ogo3Mahin ni ilu ibilẹ wa Igbo ni Ilu ibilẹ wa ilu ti Olorun tedo di alagbara Majemu isaju baje4Baba maṣe ba ayo wa jẹ ki awa le ma sogo ni ilu Zion Toju gbogbo ọmọ ZionAmin.About this hymnWritten byProphet MennaryORIN ALORE ZION C/S Ps 48 12Similar hymns53Mimo mimo loro Olorun, O f'oro re senu ElisaOrin Ijo Zion202Ilu mimo ti a ko tedoOrin Ijo Zion105Wo kọkọrọ ọrun to duroOrin Ijo Zion185Ẹ bẹrẹ mọlẹ ki ẹ gbe agbelebu Jesu1988 · Orin Ijo Zion Previous147 · Olorun Elisha iwo ni OlorunNext 149 · Ijoba-Aiye di ti Oluwa