No. 105 · Orin Ijo Zion · Orin IsipayaWo kọkọrọ ọrun to duroLyrics1Wo kọkọrọ ọrun to duro Ninu ilu adura ẹri Ohun alayọ pupọ lo wa Ninu kọkọrọ to duro.2Kọkọrọ to wa ni Tẹmpili yi Ninu rẹ ni ọgbọn gbe wa Ninu rẹ ni imisi gbe wa Ninu rẹ ni ẹkọ gbe wa.3Kọkọrọ na duro ti Tẹmpili Ọwọ kan nsi onti Bi o ba ti si ogo yio de Ba gbogbo awọn ọmọ ẹri.4Kọkọrọ na lo nti aisan O nti ogun eşu kuro O nşi ọna ọrun silę O nfun wa ni ọgbọn ọrun.5Kọkọrọ ti Peter ri nigbani Ti ọmọ araiye sọnu Ọlọrun fi fun awa ewe Lati fi ma şogo.Amin.About this hymnWritten byProphet MennaryORIN MIMỌ —Matt. 16 : 19Similar hymns148Ero ya wa wo ilu ogo (2ce)Orin Ijo Zion150Alapandede ti te ite re (2ce)Orin Ijo Zion53Mimo mimo loro Olorun, O f'oro re senu ElisaOrin Ijo Zion216Biagborin ti mi hele s'eti pa odoOrin Ijo Zion Previous104 · Iwọ oşupa OlogoNext 106 · Ha! Eleda mi mo ke pe o