No. 158 · Orin IkilọEso Israel MejilaLyrics1Eso Israel Mejila Ikan soso layanfe Awon Mokanla iyokun Si nkun fu ibinu2Jese bimo pupo Olorun ko won loba Dafidi omo kekere o La fororo yan3Solomon layanfe Ti dafidi yan loba Nitori Emi Alore o To wa ninu re.4Joseph nla ala rere Awon Egbon re si nbinu Nwon nse ilara re titi Nwon nta soko eru.5Enyin ayanfe Olorun Bi aiye npon nyin e mayo Nigbati ise nyin ba pe, o Nwon yio korira yin.Amin.About this hymnWritten byProphet MennarySAINARY HOLY CENTRESimilar hymns183Wo bi ifẹ aye ti n fa ọOrin Ikilọ62Ẹmi gbe mi bi edidi si ayeOrin Ikilọ7Afurugbin oro Olorun1964 · Orin Ikilọ82Ẹnyin ijọ OnigbagbọOrin Ikilọ Previous157 · Kristi omo Baba, mo wa be oNext 159 · Bi ala ba ko mi