No. 62 · Orin IkilọẸmi gbe mi bi edidi si ayeLyrics1Ẹmi gbe mi bi edidi si aye Aiye sin nta ọfa ẹsin si mi Bi mọ ba le la sannma aiye koja O mayọ O2Ẹmi mu mi rin iranjo Aiya nbinu Ẹmi simirọ si Zioni Aiye nsata Bi mọ ba le la Sanma aiye koja O mayọ3Mo fọwọ kan mamoni Aiye nbinu Mo fii mamoni silẹ aiye nsta Bi mo ba le la sanma aye koja O mayọ4Ko si ọrẹ bi Jẹsu laiye mo Ọrẹ bi keni lọpọ laiye Mo ba ọrẹ aiye rin Wọn nrẹ mi jẹ5Ko si Iyawo bi Serah laiye mọ Iyawo bi deliah lokun laiye Nwọn ndẹ awọn wọn lati mu akọni6Jakọbu fawọ Esau gbabukun Omi Okẹ darapọ mọ taiye Ẹni emi parade Seran ara7Eleran ara nba eni emi jagun Eleran fi ija gba ibukun Ode ma le adaba sora8Mo fe ogo aye fun itura ni Itura aye padi di ilera iku Bi o mo ba le sama aye koja E mayo oAminAbout this hymnWritten byProphet MennaryORIN MIMO EXM. SAINARY ALORE JESUSimilar hymns183Wo bi ifẹ aye ti n fa ọOrin Ikilọ140Mase tori Mamoni alaistitoOrin Ikilọ158Eso Israel MejilaOrin Ikilọ16Awọn kan ntẹle eşuOrin Ikilọ Previous61 · Bi igbagbo mi bape lodo re OluwaNext 63 · A! iwọ igi yi : A! igi yi