No. 159 · Orin Isipaya · Orin AduraBi ala ba ko miLyrics1Bi ala ba ko mi Bi iran ba ko mi Ki ni emi yio se loke Oluwa Olorun eleda mi Ma se je ki iran ko mi Ki nle ti ipa ala de odo re2Esu nfurugbin ese Ese nfurugbin iku Lati fi ko enia lorun Ki won male lagbara Lati ru ajaga Jesu Olorun eleda somi3Baba- fi iran gbe mi ro Fi ala simi niye Jowo fi emi re to mi Maje kesu ati ese Gbe mi subu loke yi Jowo Iran re gbe mi ro4Iran ko Solu sile O sin deni irera Lori, oke Olorun Joseph la ala rere O sin deni ologo Ninu idile Israel.Amin.About this hymnWritten byProphet MennaryORIN MIMO Sainary AloreSimilar hymns59Oju awọn Nasiry, kole ku fun iran ririOrin Isipaya197Emi-Mimo gbe mi gun okeOrin Isipaya92Gbati mo wa ninu ẹmi OluwaOrin Isipaya57Ninu awosanma to duroOrin Isipaya Previous158 · Eso Israel MejilaNext 160 · Oko igbala jade nilu Eko wa