No. 172Eli o Omo SioniLyrics1Eli o Omo Sion (2x) Adaba merin duro si temple Won nkoni2Eli o Eri Alo (2x) Dahovacy duro si temple O nkoni3Eli o Dahovacy Eli o Eri Alo Dahovacy duro si temple O nkoni4Elo o Mennary Alau (2x) Misiry duro si tempili O nriran.5Eli o Omo Sioni (2x) Odo aguntan duro lori oke- O nkigbe6Rori o Omo Zion (2x) Odo aguntan nbo lori oke- O nkigbe7Eli o Mennary alau (2x) Dahovacy duro si tempili O nkoni8Eli o Merharmar alau (2x) Misiry duro si tempili O nriran9Eli o omo Sion (2x) Adaba Merin nfo lori oke iri AloAminAbout this hymnWritten byProphet MennaryYear1964Similar hymns1Opo eri te ro - Awon omo Eri nsokun1957 · Orin Iyin ati Ọpẹ6Geography ọrun ti Ọlọrun fi fun wa1959 · Orin Iwa Mimọ21Mo ngbọ ọrọ edidi ọrun 1957 · Orin Woli, Iran ati Ẹmi Mimọ63Mo fi duru mi kọ igi willoh (2ce.)1964 · Orin Ekun Previous171 · O o o ma gun esin lo Next 173 · Jesu to ku ti ye