No. 195 · Orin AjindeJesu ti jinde mojo moyoLyrics1Jesu ti jinde o Mojo moyo Angeli bami gbe ayo mi ga Jesu ti jinde o mojo moyo Angeli bami gbayo mi ga2Wo awon adaba ninu sama Won fiye nwo ara won, won njo Nwon nkorin ayo Ajinde Angeli bami gbayo miga3Angeli meji leti boji Ogo won ntan yi boji ka Awon Olusi ri imole won Niberu won dojubole4Maria sare lo siboji O ri Olugbala nibe O sunmo Jesu o pe Rabbi Angeli bami Gbayo mi ga5Eli eli lori oke ipe dun ara san Awon elese dojubole Nigbati Jesu jindeAminAbout this hymnWritten byProphet MennarySimilar hymns194Jesu to ku ti yeOrin Ajinde87Mo ri Ọrọ kan gbọ ninu BibeliOrin Ajinde141MARIA MIMO -wo omo re oOrin Ajinde89Ọmọ Baba awa mbẹ ỌOrin Ajinde Previous194 · Jesu to ku ti yeNext 196 · Eje Jesu yi ti to fun igbala mi