No. 212 · Orin IdandeEri ti mo ri ni mo nlo BabaLyrics1Eri to mo ri ni mo nlo Baba Oro Jehovah ni mo nso Edidi igbagbo ni mo fi han fun aye. Oro igbala ni mo nso Eri tire da so fun mi Edidi ti o mo tu fun mi Ijinle Oro ni mo nso.2Ijoye aye ngbogun o tori mi Imo ara ngbogun, o tori mi Nwon nfe lati gba edidi yi Kuro lowo mi O Eledumare gba mi o3Imo yi di owo re O Baba, Baba toju omo re o laiye o Woli eke ti poju l'aye o Ogbon aye ti poju lodo wa Nwon nfe lati ke edidi yi Kuro lowo wa O Olorun Elijah gba wa O4Oro otito ti bo sodo mi Awa ti ri ifihan ododo Ona igbala lawa nrin o Baba fun wa nigboya oro re Nwon nfe lati ke oro otito Kuro lodo wa O Olorun Elijah gba wa O.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryYear1955Similar hymns158Alore Ọlọrun Simiro1957 · Orin Idande182Olorun mi!! yara gba mi olorun mi!Orin Idande69Ẹnyin ara oke SioniOrin Idande136Olorun igbalaOrin Idande Previous211 · Gbogbo ara mi ninu OluwaNext 213 · Olorun Oluwa Mo dupe lowo re