No. 213Olorun Oluwa Mo dupe lowo reLyrics1Olorun Oluwa Mo dupe lowo re Gbati o fi eri re fun wa Ninu irin ajo wa2Mo ri oro re gba Ninu odunawa yi Lati Kede fun gbogbo eda Pe ki aje ma je oye3Ohun jéjé kan sọ Si mi leti wipe Gbogbo ara aiye ti foju Nipa aje to joba4A ki fi owo j'oye Ni ile Olorun mi Beni a ki fi ola na ipo Lodo oga ogo.5Gbogbo aladamo To nfi owo je oye Nibo ni enyin yio lo sa si? Lodo idajo Baba6Gbogbo oye ti o wa Ni igbagbo isaju Olorun lo nran emi re Lati fi won je oye7Mo de arin enia mi Mo kede oro yi Nwon sata mi, won kegan mi Nwon pe mi ni were.8Mo de odo ariran aye Mo soro yi fun won Nwon sata mi, nwon kegan mi Nwon fun mi ni pasan9Gbogbo onigbagbo Ema fi owo je oye Emase fi ero ara Gbe enikan si oye10Mo de odo Woli aiye Lati soro otito Nwon fi mi le omo-Ogun lowo Omo-Ogun won na mi.11Mo dupe lowo re Olorun Oluwa 'Gbati mo soro re fun aiye Ti ara aiye si pa mi.12Jésù omọ Baba Jeki nje ni iya re Ki emi ku ninu iku re Kin le ba o jindeAminAbout this hymnWritten byProphet MennaryYear1956Similar hymns1Opo eri te ro - Awon omo Eri nsokun1957 · Orin Iyin ati Ọpẹ6Geography ọrun ti Ọlọrun fi fun wa1959 · Orin Ikilọ20Romicinah - Mary Alau-Dauher1956 · Orin Asotele21Mo ngbọ ọrọ edidi ọrun 1957 · Orin Asotele Previous212 · Eri ti mo ri ni mo nlo BabaNext 214 · Jesu omo Baba temi di owo re