No. 214Jesu omo Baba temi di owo reLyrics1Jesu omo Baba temi di owo re Majeki emi sina ninu Ogbon re Majeki are mu mi lona ajo yi2Wo gbogbo igbi aiye ti nyi mi kiri O nbu niwaju mi ati lehin mi Majeki igbi aiye le bori mi3Igbi omi pupo lo wa lona yi Awon alagbara nsanre yi mi ka Jesu omo Baba se ona mi ni ire4Nitori oro re aiye nkegan mi Mo si di ajoji si ara ilu mi Olorun Elijah temi dowo re5Oke pupo lo wa, ti ki se tire Igi pupo lo hu ti iwo ko gbin Oye pupo lo wati iwo ko yan6Jesu Omo Baba wo oke won yi Ti nwon si ngberaga ninu imo esu. Olorun Elisha wa ke won lule7Gbogbo ero ara ti araiye nro Gbogbo idajo eke ti ara aiye nse Jesu Omo Baba ko ma fi owo siAbout this hymnWritten byProphet MennaryYear1964TuneOLODUMARE GBO OHUN EBE MISimilar hymns1Opo eri te ro - Awon omo Eri nsokun1957 · Orin Iyin ati Ọpẹ6Geography ọrun ti Ọlọrun fi fun wa1959 · Orin Ikilọ21Mo ngbọ ọrọ edidi ọrun 1957 · Orin Asotele63Mo fi duru mi kọ igi willoh (2ce.)1964 · Orin Ekun Alore Previous213 · Olorun Oluwa Mo dupe lowo reNext 215 · Olorun alagbara Ojo aye mi di owo re