No. 215Olorun alagbara Ojo aye mi di owo reLyrics1Olorun alagbara Ojo aye mi di owo re Majeki emi si O gbo Ninu onje to fun mi Majeki onidajo aye Gba onje re lowo mi2Mo di eni ti a npa ose si Gbati mo nje onje orun Mo di eni ti a fi se eleya Nipa onje orun to fun mi Majeki onidajo aiye Gba onje re lowo mi3Ninu onje Orun ti mo je Ni mo ti ngboro Olorun O nso nipa ibere aiye Ati bi opin aiye ti ri Olorun Olugbala Fi iran Orun han mi4Gbati mo nje onje orun Mo soro orun fun ara aiye Aiye nbu mi, nwon na mi Mo di eni irira fun won Adura mi si nipe Baba fi onje orun bo mi.5Mo ri ite mimo kan Nibe l'awon woli wa Omi iye wa lodo won Mo mu ninu omi ıye na O fun okan mi ni isimi O si fun mi ni itura6Mo ri awosanma kan Lojo ketadilogbon Ninu efa to koja Mo gbo ohun to so si mi Wipe omo mi gba edidi K'o si gbe agbelebu.7Gbati mo gbe agbelebu Lati soro Olorun Ijoye aiye ngan mi Mo di ajeji si ara mi Adura mi si nipe Baba se omo re logo.AminAbout this hymnWritten byProphet Mennary Previous214 · Jesu omo Baba temi di owo reNext 216 · Olorun mi ebe ni mo nbe O