No. 216Olorun mi ebe ni mo nbe OLyrics1Olorun mi ebe ni mo nbe O Majeki ogbon aiye da mu mi Majeki emi le si oro so Bi iwo ba wi je ki n le mo ohun re2Ise ti o ran mi ni mo nje fun aiye Aye nba mi ja, nwon nse mi nise Mo di eniti nrin laiba egbe jo Nitori ajaga re ti mo ngbe3Ninu ajaga re ti mo ngbe yi Jeki nle je iya to wå ninu re Jeki nle ri ogo t'o wa ninu re Majeki emi ku laipe iye ojo4Onigbagbo to ni ogbo igo Ati Keferi to ni ofo igo Eyara wa gba igo titun yi K'e si gba otin wain titun sinu re5Gbati mo de arin ijosin Kan O gbo igo pupo lo wa nibe Mo da otin wain titun sinu won Otin wain titun fo ogbo igo6Adura mi si Olorun si ni pe Ki aiye, ma pa a l'aipe iye ojo. Bi mo ba wa ninu ide aye Ran angeli re lati tu mi sileAminAbout this hymnWritten byProphet Mennary Previous215 · Olorun alagbara Ojo aye mi di owo reNext 217 · Gbati mo wa laiye'aiye feran mi