No. 301Ohun oro igbagbo lileLyrics1Ohun oro igbagbo lile Ti o ti oke orun wa O damu pupo ologbon Alaimokan mokan2Oro eri to ti oke wa Onkolu ide irin O nfo gbogbo amo kuro Lara irin lile3Oro Baba to ti Oke wa Tani fe tapa si Eni ba gan oro Baba Yo di omo egbe4Kristi okuta iyebiye E mase ko oro re Eni ba kose lara re Kristi yo lo tutu5Nikehin ojo aye wa Baba yo mü oso si apa kan Yo mu aguntan si apa kan Yo fi ina sun aje6Lori apata pipe yi Ti Kristi gbe kale Eni ba kose lara re Yo je omo orun apadiAminAbout this hymnWritten byProphet MennaryYear1956TuneAyo kun okan loniORO YE ONI AGBARAORIN MIMO NI SUNDAY 22/10/1956Similar hymns1Opo eri te ro - Awon omo Eri nsokun1957 · Orin Iyin ati Ọpẹ4Oba Oloro – foro sakoso lori Ijo Tire1957 · Orin Ijo Zion8Wo pẹtẹlẹ ologo didan1957 · Orin Isipaya9Fi ara re fun Olorun1957 · Orin Isegun Previous300 · Aye lajo mi orun ni ilu mi oNext 302 · Lori oke apata Kristi