No. 302Lori oke apata KristiLyrics1Lori Oke apata Kristi Nibe ni Olorun joba o Mo yo pupo2Oro to ti ori oke wa O n gbe mi ro' O n bi ni Subu o Ara Sora3Ipe pupo lo n so simi Jeka fi eti si ipe Olorun Gbogbo Woli4Oro pupo lo n wo inu okan Jeki a fi eti si oro Olorun O Gbogbo elemi5Emi pupo lowa laiye Emi ti Olorun yo duro Titi lailai6Lori oke ti a de yi Emi idanwo pupo lo wa o Ara sora7Gbogbo elemi fi ara bale Fi eti si ohun to ti orun wa Ara Sora8Lori oke ti a de yi Woli ti ko ba ni edidi Yo ba odo lo9Idide wa lori oke yi Isubu po lori oke yi Ara Sora10Gbogbo ogun orun duro Nwon nso simi leti wipe o Ara sora11Bi emi Olorun ba ti dide Emi Esu yo sì danwo o Ara sora12Ikore aye fere gbo tan Olododo dihamora o Ki e si sora oAminAbout this hymnWritten byProphet MennaryYear1956IKILO ATI IPEORIN MIMO NI Monday Night 22/10/56Similar hymns1Opo eri te ro - Awon omo Eri nsokun1957 · Orin Iyin ati Ọpẹ4Oba Oloro – foro sakoso lori Ijo Tire1957 · Orin Ijo Zion8Wo pẹtẹlẹ ologo didan1957 · Orin Isipaya9Fi ara re fun Olorun1957 · Orin Isegun Previous301 · Ohun oro igbagbo lileNext 303 · Aye nde Siloh lona o Baba