No. 373Kilohun to se o - lona igbala ti mo nrin oLyrics1Kilohun to se o - lona igbala ti mo nrin o Jesu Oluko rere Chr. Egun pupo lo gun mi Ise pupo lo se mi Lona igbala ti mo nrin o Omolehin mi tele mi jiya o2Kilohun ti o ri - lona iwosan ti o nrin o Jesu omo eni rere, Chr. Ise Baba ni mo nse - Tawon ju ti pa mi Lona ajo ti mo rin o Omolehin mi etele mi jiya o3Kilohun ti o ri lona ajo ti o nrin o. Moses eleri rere Chr. Ise pupo lo se mi - iya pupo lo je mi Lona ajo ti o nrin o Omo ogun Oluwa e mase ko iya o4Kilohun ti ori-lona ajo ti o nrin o Elijah omo ogun Olorun Iya pupo ni mo je - nipa Woli eke ti mo pa. Lona irin ajo ti mo re o Omo ogun Olorun etele mi jiya o5Kilohun to se o? lona irin ajo ti o nrin o Jeremiah akoni rere Chr. Woli eke ni mo ba so Awon Ju gbe mi sinu ere o Nwon kan ese mi sinu aba Akowe mi tele mi jiya o6Kilohun to se o? lona irin ajo ti o nrin o Daniel Olufe rere Mo gbadura lemeta lojo Awon Omo eke di rikisi simi Nwon gbe mi sinu iho kiniun Nipa adura eyiti mo ngba o7Kilohun to se o? lona irin ajo ti o nrin o Joahnu eleri rere Eri Phillip ni mo je - Ti Herodia bere ori mi Lona irin ajo ti mo rin o Omolehin mi etele mi jiya o.8Kilohun to se o? lona irin ajo ti o nrin o Stephen eleri ekini Oro otito ni mo so -Tawon Ju somi lokuta Lona irin ajo ti mo rin o. Omolehin etele mi jiya o.9Kilohun to se o? lona irin ajo ti o nrin o Jacob aposteli rere Eri Kristi ni mo so - Ti Herodu ba pa mi To fi ada be mi lori o Omolehin baba etele mi jiya o10Kilohun to se o? lona irin ajo ti o nrin o Peter Aposteli rere Oro iwasu ni mo so. Ti Herodu fi se mi tubu Angeli tu mi sile o Omolehin mi e ba mi yo o11Kilohun to se o? lona irin ajo ti o nrin o Johanu onisipaya rere Iran orun nimori - Ti awon Ju ba wa mi Si a erekusu patimo Omolehin mi etele mi jiya o.12Kilohun to se o? lona irin ajo ti o nrin o Paul Aposteli Oluwa Pasan Ogojidinkan lawon Ju fun mi Igba pupo loko nrin mi Lona irin ajo mo rin o Omolehin mi etele mi jiya o.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo ni Saturday Evening 3/8/57 Previous372 · Jesu Oba igbala - Jesu Oba IyeNext 374 · Eniti o se taiye