No. 374Eniti o se taiyeLyrics1Eniti o se taiye On laraiye yio fe Eniti o se ife Olorun Laraiye nkorira2Esu gbe oso dide Lati ba oloto ja Olorun gbe Woli dide Lati bi ogun esu wo3Ida Oluwa dide Ni igun merin aiye O nko mana niwaju esu Yio pa esu ati ogun re4Gbogbo Egbe Woli E gbe asia ogun soke E ko orin iyin oga ogo To se wa lomo ogun5Ari Alau Dau Salau Elisha Romelly O bu foju lu ogun esu Oju won sisu okunkun.6Edide ogun si esu Ati omolehin re Eba won ja e o bori Nipa agbara Olorun7Angeli Ologun Jade ni iwo orun O wo inu awon akoni Lati pa agbara esu8Mennah nfo mo ida O si ro doje Yio si rudi gbogbo eke Nipa Ola Arabijah.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo ni Sunday 9.a.m. 4/8/57 Tune: Olorun Oluwa T. H. S. A Previous373 · Kilohun to se o - lona igbala ti mo nrin oNext 375 · Ibasepe Mose ko wa saiye