No. 484Bi o se nlo mi lo yi OluwaLyrics1Bi o se nlo mi lo yi Oluwa O dara O dara Bi o se nto mi lo yi Oluwa O dara O dara.2Ko si eniti iwo nto to ndese Nigbati iwo je Oluko fun Sugbon bi iwo fi sile gere Esu yio ran ese si.3Gbati mo ba de ile adura Re Emi re, si nba mi jeri Pe omo Olorun ni mo nse O dara O dara.4Ohun pupo ni iwo nse fun mi Nitoto ti iwo nto mi O nso mi losan ati loru O dara O dara.5O ko fi ebun ini Re je mi niya Nitoto ti iwo nto mi Nko sagbe ki nto je onje O dara o dara.6Bi oti nlo mi loyi Jehovah Owo ati omo nikan ni nkoni to Bi o se ti ebun ini Re iyoku Iwo nse fun mi ni die die.7Iwo ran oro Re simi sinu O si npin orin Re si ete mi O da ewa Re simi lara O dara O aara.8Gbogbo ofin mimo Re to fun mi nso Mase jeki nru ikan ninu re So ofin Sainary Re mo aiya mi Ki nle ma ka lojojo9Gba mi lowo pansaga aiye Gba mi lowo agidi ija aiye Mase jeki nru ofin ni lilo to nlo mi Fi emi Re nikan ma to mi.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Previous483 · Kristi ti ara lati orun waNext 485 · Wo aguntan to joko leti Odo Efrata