No. 508Nigba aro ati ayoLyrics1Nigba aro ati ayo Lowo Olorun lo ti wa Nigba ekun ati ayo Lowo re ni gbogo re ti wa2Olorun ni ibi oni ire Lati fifun awo Enito gba ire yio ma yo Eni gba ibi yio ma kedun3Ko si bi orun ti le ran to Ki ikuku die ma wa Ko si bi aye wa ti le wa to Ki igba ekun re ma wa4Igba kiko okuta danu Igba kiko okuta jo Igba ibimo ati iku omo Ko si Okan ti a gbodo gan.5Iran kan nlo iran kan mbo Aiye duro titi lai Olorun gbon ju gbogbo aiye Akole ko Olorun logbon.6Olorun fi aye fun esu Lati lo dan Jobu wo Olorun si tun gba Jobu Kuro ninu idanwo esu.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Previous507 · Lori Oke mo wa yi oNext 509 · Ko orin Ogo - korin huriamu