
No. 59 · Orin Isipaya · Orin Asotele
Oju awọn Nasiry, kole ku fun iran riri
Lyrics
Chorus
Iwọ ọrọ aiye, nko ni fi ọ șe Iwọ ọrọ Ọlọrun șa simi laiya mi Inu awọn Woli ni kanga ti ki fọ.
Chorus
Iwọ ọrọ aiye, etc.
Chorus
Iwọ ọrọ aiye, etc.
Chorus
Iwọ ọrọ aiye, etc.
Chorus
Iwọ ọrọ aiye, nko ni fi ọ șe Iwọ ọrọ Ọlọrun, sa simi laiya mi Inu awọn Woli, ni kanga ti ki fọ.
Amin.
About this hymn
- Written by
- Prophet Mennary
ORIN MIMỌ SAINARY ALORE
