No. 66 · Orin Ogun Ẹmi ati Igbala · Orin AduraBi mo ti nnaga nwa ogo ọrunLyrics1Bi mo ti nnaga nwa ogo ọrun Bẹni eşu nnaga nwa mi Ha! Ọlọrun maşe fi mi han Fun eşu lati ri.2Mo sare duro silẹ ẹmi Ki eşu ma le ri mi Eşu si nran awọn ọmọ rẹ Lati ma wa mi kiri.3Ẹ jọ ọmọ eşu, ija ọmọ eşu To fi nlepa awọn ayanfẹ Baba maşe jẹki ikọ eşu Le rimi bi şubu.4Orin Sainary rẹ ti o fun mi Lati fi kọ gbogbo aiye On ni eşu nde lọna yi Baba jọwọ tu silẹ.5Nigbati mo ro ti idanwo Ti o wa ninu igbagbọ yi Amure si tubọ lara mi Mo ko aşọ ogo mi silẹ.6Ara mi ko lelẹ, nitori igbogun eşu Larin ọmọ lẹhin rẹ Wọ to da Peter nide ninu tumbu Da wa nide lọwọ aiye.7Eşu bo gbogbo oku mọlẹ Ki wọn ma le jinde O ran Jesu fọ bode na Gbogbo oku mimọ si ye.8Orin Sainary ti eşu nde lọna Jọwọ ba wa tu silẹ Ran Angeli rẹ lati fọ iditẹ aiye Korin Sainary le jade.Amin.About this hymnWritten byProphet MennaryORIN MIMỌSimilar hymns2Bi o se da mi si Oluwa Orin Adura3Iwo oro Olorun - Ogbon ati oke waOrin Ikede Oro Olorun4Oba Oloro – foro sakoso lori Ijo TireOrin Adura7Ẹmi gbe mi bi edidi si ayeOrin Ogun Ẹmi ati Igbala Previous65 · Iwọ nikan loju mi jọ loju Oluwa (2ce.)Next 67 · Oju Kristi ni oju Adaba mi