No. 60 · Orin IkilọWiri!!! lese orun woleLyrics1Wiriwiri - wiri wiri Lẹşẹ ero ọrun nwọle Lati ihin rere tọ ara oke Ẹri wa.2Ẹnyin ikọla at’ alaikọla Ẹ yara wọle wa (2ce.) Lati wa gbọ Ihinrere Lẹnu awọn Alore.3Ọlọrun ọlọrọ Ọba Arabijah Mo kigbe pe Ọ, (2ce.) Maşe jẹki iri rẹ da kuro loke ẹri.4Niwaju itẹ rẹ Oluwa Ni mo duro si, (2ce.) Maşe jẹki nle şogo Rekọja la rẹ.5Mimọ mimọ mimọ mimọ Ni iri ọrun ti mo nri (2ce.) Baba jẹki nle jẹ mimọ Bi awọn ijọ tọrun.Amin.About this hymnWritten byProphet MennaryYear1957ORIN MIMỌ SAINARY ALORESimilar hymns31Geography ọrun ti Ọlọrun fi fun wa1959 · Orin Ikilọ173E fi ayo wole Adura OlorunOrin Ikilọ169Isodomo O awa omo isodomoOrin Ikilọ66Jerusalemu tọrun ti de oOrin Ikilọ Previous59 · Oju awọn Nasiry, kole ku fun iran ririNext 61 · Bi igbagbo mi bape lodo re Oluwa