No. 74 · Orin AsoteleRomicinah - Mary Alau-DauherLyrics1Romicinah - Mary Alau-Dauher Menah Dau Lau Micinah.2Aiye nkọja lọ, ọjọ fẹrẹ wọ Gbogbo ikuku mbọ oju ọjọ Aiye nkọja lọ.3Mini Hadaulau - Remily Hadalau Mini Ari Alau-Dau Calau Dalau4Ijọba oke yi - lemi ni ipin si Emi ko ni ipin si ijọba t' aiye yi.5Rabbi Alaudaulau - Menah lau dalau Ceriminnah alauda - Rabbi alaudalau.6Ọrọ baba oke - ọmọ aiye yo kọ Yo di ara ọmọ ọrun. Yo si ma ba gbe.7Emi Siloh de Ngo ya ọmọ si Baba - ngo ya baba si ọmọ N o fọju ijọba aiye.8Oro Baba oke, omo aiye yio ko Yoo di ara omo orun yio si ma ba gbe9Arabijah loro mi-Mori lori omi Eni doju ija komi apata yo kolu10Mo wa lobiri aiye, mo wa loke nile Mo gbin okuta si Sioni e sora bi e ti mole11Eli o Elijah lau Elio yarabi alau Edidi oro Siloh de Eli o Raibi alau.About this hymnWritten byProphet MennaryYear1956ORIN MIMỌ SAINARY ALORE T. H. R. 3/12/56Written on 3 December 1956.Similar hymns155Lori oke Rama - lori oke asotele1957 · Orin Asotele119Wo Woli Siloh to ti Judiah sọkalẹ1958 · Orin Asotele51Mo gbọ ọrọ edidi ọrun 1957 · Orin Asotele36Wo gbogbo egbe Woli to padeOrin Asotele Previous73 · Kọrin iwọ agan ti ko biNext 75 · Igba ogun ni ki Woli ja