No. 83 · Orin AjindeAwa ọmọ kekekeLyrics1Awa ọmọ kekeke Ti abi ninu Kristi fun Ọlọrun Ẹjẹ ka șe iranti - ọlanla ẹniti o bi wa Fun Jehovah Ọlọrun Ki așe ifẹ Rẹ.2Ija pupọ lonja To ri awa ewe - ki a ba le la O ngbadura pupọ O ngun bi iro ẹjẹ Si nti ara rẹ jade Ki awa le ye.3Ta lo ni Adura To gun oke loru yi ? Ti Kristi ni Tkun ewo ni mo ngbọ Lori oke Rama Tkun Rakeli ni - O nșokun Ọmọ.4Tlẹșẹ bi emi Jẹ karanti Jesu to ku fun wa Ti awọn Ju kan mọ igi Ton kigbe Eli Eli Okunkun șu bo ilẹ Aira si san5Jesu ti awọn Jew mu Kan mọ agbelebu - Ti ji dide O nlọ si Galili Awọn Ọmọ ẹhin Nwọn si fi ayọ nla - jẹri Ajinde6Gbogbo awọn alaisan Ati awọn afọju - Ẹ ranti Jesu To gba wa lọwọ ẹsu Ti ko jẹki a șako Kuro lọna toro - tolọ sibi Iye.Am.n.About this hymnWritten byProphet MennaryORIN MIMỌ SAINARY ALORESimilar hymns88Ninu ajinde ekiniOrin Ajinde89Ọmọ Baba awa mbẹ ỌOrin Ajinde141MARIA MIMO -wo omo re oOrin Ajinde87Mo ri Ọrọ kan gbọ ninu BibeliOrin Ajinde Previous82 · Ẹnyin ijọ OnigbagbọNext 84 · Ha! Jesu o Jesu o Jesu