No. 104 · Orin Ekun AloreIwọ oşupa OlogoLyrics1Iwọ oşupa Ologo Siri mine Siry mene2Atipo ni mo nşe lode aiye Nko ni bugbe kan nihin yi Arabijah Arabijah.3Nko ni ibugbe kan nihin yi Ko si bujoko fun mi ni Babeli Arabijah Arabijah.4Okun pupọ ni eşu ndę silę Ipa pupọ ni eşu nde silę Eli Alau mi, Eli Alau mi.5Wo bi ẹran ara ti mba ẹmi ja Aiye nda ẹbi fun ẹmi Ọlọrun A! Ọlọrun, A! Ọlọrun.Amin.About this hymnWritten byProphet MennaryORIN MIMỌ ! Korinti 15 : 14Similar hymns147Olorun Elisha iwo ni OlorunOrin Ekun Alore120Adaba ẹri mi o, nibo lore o ?Orin Ekun Alore109Mo fi duru mi kọ igi willoh (2ce.)1964 · Orin Ekun Alore214Iku le pa mi ti ilu mi jade1998 · Orin Ekun Alore Previous103 · Gbọ orin t' awọn Angẹli nkọNext 105 · Wo kọkọrọ ọrun to duro